fọ

See also: Appendix:Variations of "fo"

Yoruba

Pronunciation

  • IPA(key): /fɔ̀/

Verb

fọ̀

  1. (chiefly CY and SEY, transitive) to say
    Synonyms: sọ, wí
    àwọn ọdẹ ń fọ̀ sí araa wọn nínú igbó ― The hunters are speaking to themselves in the forest
    Kúwẹ ti fọ̀? ― What did you say? (Èkìtì)
Usage notes
  • fọ when followed by direct object.
Derived terms

Pronunciation

  • IPA(key): /fɔ̀/

Verb

fọ̀

  1. (transitive) to wash
    Lọ́ládé ń fọ abọ́ ― Lolade is washing dishes
Usage notes
  • fọ when followed by direct object.
Derived terms

Pronunciation

  • IPA(key): /fɔ̀/

Verb

fọ̀

  1. to rush out
    ògììrì ẹsẹ̀ẹ́ fọ̀ ― The feet quickly rushed out
Usage notes
  • fọ when followed by direct object.

Verb

fọ́

  1. (transitive) to break (a vessel)[1]
    bí adìẹ́ bá dà ẹ́ lóògún nú, ìwọ náà a sì fọ́ ọ lẹ́yin ― If a hen spills your medicine, you should break its eggs (proverb on revenge)
  2. (transitive, intransitive) to destroy (a town or nation by war)[1]
    Àwọn ọmọ ogun Ìbàdàn fọ́ ìlú Èkìtì púpọ̀ láyé àtijọ́ ― In the past, soldiers of the town of Ibadan destroyed many Ekiti towns
  3. (intransitive) to become broken, to explode, to collapse
    ìgò ó fọ́ yángá ― the bottle broke into pieces totally
  4. (idiomatic) to suffer from a headache or blindness
    Ojú mi ti fọ́ ― I have become blind (literally, "my eyes have broken")
    orí ń fọ́ mi ― I have a headache (literally - "my head is breaking")
Derived terms
  • abọ́máfọ̀ọ́
  • afọ́
  • afọ́jú (“blind person”)
  • ẹ̀fọ́
  • ẹ̀fọ́rí (“headache”)
  • fọ́lé
  • fífọ́
  • orífífọ́ (“headache”)
  • ìfọ́
  • ìfọ́jú (“blindness”)

Pronunciation

  • IPA(key): /fɔ́/

Verb

fọ́

  1. (transitive) to liquefy (something)
    ọmọ́ fọ́ ẹ̀kọ mu ― The child liquefied the ẹ̀kọ and drank it
Derived terms

Pronunciation

  • IPA(key): /fɔ́/

Verb

fọ́

  1. (transitive) to slap, to hit (with a vessel)
Derived terms

Pronunciation

  • IPA(key): /fɔ́/

Verb

fọ́

  1. (transitive) to shout loudly
    Synonyms: kọ, halẹ̀, ké
    ọmọ́ fọ́ táá ― The child shouted in anger
Derived terms

Pronunciation

  • IPA(key): /fɔ́/

Verb

fọ́

  1. (intransitive) to lose weight, to shrink in body size, to emaciate
    àìsán mú kí aláìsàn fọ́ ― The illness caused the sick person to lose weight

References

  1. Crowther, Samuel (1852) A Vocabulary of the Yoruba Language‎, London: Seeleys, pages 108–9
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.