orilẹ-ede

Yoruba

Etymology

From orílẹ̀ (“socio-political or linguistic entity”) +‎ èdè (“language”), literally “A political entity consisting of different languages”

Pronunciation

  • IPA(key): /ō.ɾí.lɛ̀.è.dè/

Noun

orílẹ̀-èdè

  1. country, nation

Derived terms

  • asáwọ-orilẹ̀-èdè-mìíràn fún ààbò (“refugee”)
  • orílẹ̀-èdè aṣẹ̀ṣẹ̀-ń-dìde-nílẹ̀ (“developing country”)
  • orílẹ̀-èdè oníjọba-ajẹmọ́ba (“monarchy”)
  • orílẹ̀-èdè t'ó ti gòkè àgbà (“developed country”)
  • orílẹ̀-èdè Àmẹ́ríkà (“United States”)
  • orílẹ̀-èdè ààbò (“protectorate”)
  • ọmọ-orílẹ̀-èdè (“citizen”)
  • Àjọ orílẹ̀-èdè kọ́mọ́ńwẹ́ẹ̀tì (“Commonwealth of Nations”)
  • Àjọ Orílẹ̀-èdé Ajùmọ̀tepolẹ̀-sórílẹ̀-èdèmìíràn (“OPEC”)
  • àkọsílẹ̀-àdéhùn láàrin àwọn orílẹ̀-èdè (“treaty”)
  • àpapọ̀ ohun-àṣejáde orílẹ̀-èdè (“gross domestic product”)
  • ìjọba-àpapọ̀ orílẹ̀-èdè (“federal government”)
  • ìjọ́mọ-orílẹ̀-èdè (“citizenship”)
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.